Ìpàdé àwọn Òǹkọ̀wẹ́ ní Nàìjíríà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ní oṣù kẹfà ọdún 1962[1][2] wọ́n ṣe ìpàdé kan nípa àwọn Ìwé ÁfríkàÈdè Gẹ̀ẹ́sì, òun ni Ìpàdé àwọn òǹkọ̀wé Áfríkà àkọ́kọ́, ìpàdé náà wáyé ní Makerere University CollegeKampala, Uganda. Wọ́n pè ní "Conference of African Writers of English Expression" ní èdè òyìnbó. Congress for Cultural Freedom àti Mbari Club ni ó segbá tẹ́rù ìpàdé náà.[3][4]

Ọ̀pọ̀lopọ̀ àwọn òǹkọ̀wé tí ó gbajúmọ̀ ní Áfríkà ni ó wá sí ìpàdé náà, àwọn bi: láti West Africa Chinua Achebe, Wole Soyinka, John Pepper Clark, Obi Wali, Gabriel Okara, Christopher Okigbo, Bernard Fonlon, Frances Ademola, Cameron Duodu, Kofi Awoonor; láti South Africa: Ezekiel Mphahlele, Bloke Modisane, Lewis Nkosi, Dennis Brutus, Arthur Maimane; láti East Africa Ngũgĩ wa Thiong'o, Robert Serumaga, Rajat Neogy (ọ̀lùdásílẹ̀ Transition Magazine), Okot p'Bitek, Pio Zirimu, Grace Ogot, Rebecca Njau, David Rubadiri, Jonathan Kariara; àti Langston Hughes.[1][5][6][7][8]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 "The First Makerere African Writers Conference 1962", Makerere University Archived 2013-12-27 at the Wayback Machine..
  2. Peter Kalliney, "The Makerere generation", TLS, 6 July 2016.
  3. Obi Nwakanma, Christopher Okigbo, 1930-67: Thirsting for Sunlight, James Currey, 2010, p. 181.
  4. Mbari Club, Makerere University College. Department of Extra-Mural Studies, Congress for Cultural Freedom, Conference of African Writers of English Expression, Kampala, Uganda: Makerere University College, 1962. WorldCat
  5. Billy Kahora, "Penpoints, Gunpoints, and Dreams: A history of creative writing instruction in East Africa", Chimurenga Chronic, 18 April 2017.
  6. John Roger Kurtz, Urban Obsessions, Urban Fears: The Postcolonial Kenyan Novel, Africa World Press, 1998, pp. 15–16.
  7. Frederick Philander, "Namibian Literature at the Cross Roads", New Era, 18 April 2008. Retrieved 14 February 2023.
  8. Robert Gates, "African Writers, Readers, Historians Gather In London", PM News, 27 October 2017.