Ìwé Jóṣúà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ilẹ̀ Ìlérí.

Ìwé Joṣua ni ìwé Bibeli Mimo tó sọ̀rọ̀ nípa Jóṣúà, lẹ́yìn Mósè tó ń jẹ́ adarí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, Jóṣúà ni ó kàn tí ó darí wọn dé ilẹ̀ Kénáánì, tí ń ṣe ilẹ̀ ìlérí Ọlọ́run sí wọn. Jóṣúà, jẹ́ adarí tó ní sùúrù, tó sì jẹ́ akíkanjú ènìyàn. Abbl.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]