Ìyá

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ìyá àti ọmọ rẹ̀

Ìyá (màmá tabi mọ̀nmọ́n) ni òbí tó jẹ́ obìnrin èèyàn kan. Ìyá àti bàbá jẹ́ òbí fún ọmọ tàbí ènìyàn kan. Àwọn Yorùbá bọ, wọ́n ní, " Ìyá ni wúrà"... Bẹ́ẹ̀ náà tún ni, " Gbẹ̀dẹ̀ bí Ogún Ìyá, aninilára bí Ogún Baba". Ìyá jẹ́ ọ̀kan gbógì tí wọn kò ṣéé fojú rénà láwùjọ, ní ìlú, Ìpínlè pàápàá jùlọ lagbaye. Ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ Ìgbà, ìyá ló máa ń bí ọmọ fún ara rẹ̀, nígbà mìíràn ó lè gba ọmọ ẹlòmíràn bí ọmọ rẹ̀ tàbí kí ó gba ọmọ ẹlòmíràn tọ́.[1] [2]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "MOTHER - meaning in the Cambridge English Dictionary". Google. Retrieved 2020-01-10. 
  2. "Mother". Lexico Dictionaries | English. Archived from the original on 2020-02-02. Retrieved 2020-01-10.