Òṣèlúaráìlú
Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Òṣèlúaráìlú je ijoba oniselu aralu boya to ba wa taara latowo awon aralu tabi won fun awon asoju won lase ninu idiboyan lati lo agbara yi. Ni ede Geesi o n je democracy to wa lati oro ede Griiki: δημοκρατία - (dēmokratía) to tunmo si "agbara aralu"[1] eyi ti won yi wa lati δῆμος (dêmos), "aralu" ati κράτος (krátos) "agbara" larin orundun ikarun-ikerin kJ lati tokasi iru sistemu oniselu to wa nigbana ni awon ilu-orile-ede Grisi, pataki ni Ateni Atijo leyin rogbodiyan odun 508 kJ.
| Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |