Ẹgbẹ́ Rẹ̀públíkánì (USA)
Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ẹgbẹ́ Rẹ̀públíkánì (Republican Party) je ikan awon egbe oloselu meji pataki loni ni orile-ede Amerika. O je didasile latowo awon alakitiyan olodi-okoeru ni 1854, won mo si GOP to duro fun Grand Old Party, botilejepe o ojo-ori re kere si egbe oloselu ekeji re. Eto egbe re je gbigba pe o wa ni otun agede ni bi oselu ti Amerika.
| Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi [àtúnṣe]