Ẹyin

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àyọkà yìí jẹ mọ́ nípa biological eggs. Fún eggs as food, ẹ wo: ẹyin gẹ́gẹ́ bí óúnjẹ. Fún other uses, ẹ wo: Egg (disambiguation).
Eggs of various birds, a reptile, various cartilaginous fish, a cuttlefish and various butterflies and moths. (Click on image for key)
Diagram of a chicken egg in its 9th day. Membranes: allantois, chorion, amnion, and vitellus/ yolk.
Six commercial eggs Àdàkọ:Mdash view from the top against a white background

Ẹyin ni a lè pe ní àpò-lùkẹ́ tomi-jẹ̀jẹ̀ tí ó dara pọ̀ mọ́ra wọn tí ó ń di òròmọdìyẹ nígbà tí ó bá ti tó àsìkò rẹ̀.[1][2] Púpọ̀ awọn kòkòrò tí wọ́n jẹ́ elégungun lẹ́yìn yàtọ̀ sí ènìyàn ni wọ́n sábà ma ń sábà ye ẹyin

Àwọn ẹranko afàyàfà bí ejò tabí ọ̀nì àti ẹyẹ a máa ye ẹyin tiwọn sórí ọ̀dàn, wọn kìí ye sínú [[om]. Ìrísí àwọn yin wọn ma ń yatọ̀ sírá wọn, àmọ́ gbogbo eyin wọn ló ma ń lépo lára. Yálà ẹyin náà nípọn kò nípọ, gbogbo ibintí àwọn ẹranko wọ̀nyí yóò bá ye ẹyin sí lórí ọ̀dàn, ibẹ̀ gbọ̀dọ̀ ma lọ́wọ́rọ́ tí yóò sìa dàgbà si. Bí ẹyin náà bá ti wá gbó dáa dáa, ẹranko inú Eyin náà yóò fọ́ ẹyin náà jáde. Ẹyin tí ó tóbi jùlọ nínú àwọn ẹyin ni ẹyin ẹja Whale Shark tí ó tó ìwọ̀n 30 cm × 14 cm × 9 cm (11.8 in × 5.5 in × 3.5 in). [3] Ẹja Whale shark kìí yé ẹyin tìrẹ nítorí kìí ṣe ẹja jomi-jòkè, inú rẹ̀ ni ó ti ùn pa ọmọ rẹ̀. Ẹyin ẹyẹ ògòngò tí ẹyin tirẹ̀ tó 1.5 kg (3.3 lb) àti 17.8 cm × 14 cm (7.0 in × 5.5 in), jẹ́ ẹyin Ẹyẹ tí ó tòbí jùlọ ní gbogbo agbáyé,[4].eye asoso ni eyin re kere julo ni agbaye, ti iwon re je 6.35–11.4 millimetres (0.250–0.449 in). eyin ti awon eranko afayafa, eja, kokoro ati awon eranko tiko legungun ma n ye kere julo si ti asoso.


Àwọn itọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Structure of the Egg - Incubation and Embryology". University of Illinois Extension. Retrieved 2023-06-14. 
  2. "Egg - Definition, Characteristics, & Nutritional Content". Encyclopedia Britannica. 1999-07-26. Retrieved 2023-06-14. 
  3. "Whale Shark – Cartilaginous Fish". SeaWorld Parks & Entertainment. Archived from the original on 2014-06-09. Retrieved 2014-06-26.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. D.R. Khanna (1 January 2005). Biology of Birds. Discovery Publishing House. p. 130. ISBN 978-81-7141-933-3. https://books.google.com/books?id=fDblIChi7KwC&pg=PA130.