.cs

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
.cs
Introducedca. 1990
TLD typeCountry code top-level domain
StatusDiscontinued
RegistryNone
SponsorNone
Intended useEntities connected with  Czechoslovakia (originally, until deleted) and later Àdàkọ:SCG (reserved, but never used)
Actual useWas fairly heavily used in Czechoslovakia until discontinued in favor of .cz and .sk; never used while Serbia and Montenegro existed
Registration restrictionsNo registrations are now taking place
StructureNot in root
Dispute policiesNone
WebsiteNone

.cs je fun opo odun amioro orile-ede top-level domain (ccTLD) fun Czechoslovakia. Sugbon, orile-ede na tuka si Czech Republic ati Slovakia ni 1993, awon orile-ede mejeji yi si gba ccTLDs ti won otooto: .cz ati .sk nitelerawon. Ilo .cs wa dopin die die, o si je pipare patapata ni January 1995.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]