African Sources for African History

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
African Sources for African History  
Abbreviated title(s) Afr. Sources Afr. Hist.
Discipline History
Language
Publication details
Publisher Brill
Publication history Since 2001
Indexing
ISSN Àdàkọ:Infobox journal/ISSN-eISSNÀdàkọ:Infobox journal/ISSN-eISSNÀdàkọ:Infobox journal/ISSN-eISSNÀdàkọ:Infobox journal/ISSN-eISSNÀdàkọ:Infobox journal/ISSN-eISSNÀdàkọ:Infobox journal/ISSN-eISSNÀdàkọ:Infobox journal/ISSN-eISSNÀdàkọ:Infobox journal/ISSN-eISSNÀdàkọ:Infobox journal/ISSN-eISSNÀdàkọ:Infobox journal/ISSN-eISSN
Links

African Sources for African History jẹ́ àwọn ìwé tí Brill kọ láti sọ nípa àwọn ìtàn Áfríkà pàápàá jùlọ, ní apá sub-Saharan Africa.[1] Ìdí tí wọ́n fi ń kọ àwọn ìwé náà ni láti mú kí àwọn ìtàn àkọ́lẹ̀ nípa Áfríkà pọ̀ sí, àti láti ṣe àtúnṣe sí àwọn ìtàn tí àwọn àìtọ́ tí àwọn òyìnbó ti kọ nípa Áfríkà.

Ìwé tí wọ́n kọ́kọ́ gbé jáde ní 2001 Somono Bala of the Upper Niger, ìtàn nípa àwọn apẹja, wọ́n sì tún ìwé náà láti èdè òyìnbó sí èdè Maninka fún àwọn ènìyàn láti kà.

Àkòrí àwọn tí wọ́n ti kọ[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • The Epic of Sumanguru Kante
  • Les mémoires de Maalaŋ Galisa sur le royaume confédéré du Kaabu
  • Guidance (Uwongozi) by Sheikh al-Amin Mazrui: Selections from the First Swahili Islamic Newspaper
  • Print Culture and the First Yoruba Novel
  • Sukuma Labor Songs from Western Tanzania
  • Writing for Kenya
  • Tarikh Mandinka de Bijini (Guinée-Bissau)
  • Entretiens avec Bala Kanté
  • The Pen-Pictures of Modern Africans and African Celebrities by Charles Francis Hutchison
  • Servants of the Sharia
  • Djinns, Stars and Warriors
  • Telling Our Own Stories
  • Les Rois des Tambours au Haayre
  • Marita: or the Folly of Love
  • Somono Bala of the Upper Niger

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. African Sources for African History Brill, 2014. Retrieved 17 May 2014.