Ajaland

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ajaland jẹ́ àgbègbè kan tí àwọn Ẹyà Aja ń gbé ní Benin àti Togo, Ìwọòrùn Áfíríkà. Ní àárín ọdún 1500AD sí 1700AD, àgbègbè náà jẹ́ àárín kí kọ́ni lẹ́rú Atlantic Slave Trade. Àgbègbè yìí wà lábẹ́ ìṣàkóso Ijoba Whydah àti lábé ìjọba Allada. Síbẹ̀síbẹ̀, bí David Ross ṣe sọ,[1] àwọn ọba àgbègbè yìí kò dárí gbogbo ilẹ̀ agbègbè náà, àwọn ilẹ̀ díè míràn wà lábẹ́ àwọn ọba míràn ní àyíká.

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Ross, David. "Robert Norris, Agaja, and the Dahomean Conquest of Allada and Whydah". in History in Africa. 16 (1989), 311-324.