Alemitu Tariku

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Alemitu Tariku
Òrọ̀ ẹni
Orúkọ àbísọAlemitu Tariku Olana
Ọmọorílẹ̀-èdèEthiópíàn
Ọjọ́ìbí28 Oṣù Kẹ̀sán 2000 (2000-09-28) (ọmọ ọdún 23)
Sport
Orílẹ̀-èdèEthiópíà
Erẹ́ìdárayáAthletics
Event(s)3000m, 5000m

Alemitu Tariku Olana ti a bini ọjọ kèji dinlọgbọn óṣu september ni ọdun 2000 jẹ elere to man sare fun idije ti ilẹ Ethiópíà[1][2][3][4].

Iṣẹ ati Ipa Àràbinrin naa[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Alemitu kopa ninu idije agbaye ti ilu Aarhus ni ọdun 2019 nibi ti arabinrin naa gba ami ẹyẹ ti silver ninu U20 ni iṣẹju 20:50 lẹyin naa logba ami ẹyẹ ti gold pẹlu team rẹ to wa lati ilu Ethiopia[5][6][7].

Arabinrin naa dije ninu ere idije junior ti ilẹ afirica ni ilu abidjan nibi toti yege ninu 3000 meter dash ni iṣẹju 9:33:53[8][9].

Ami Ẹyẹ ati Idanilọla[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọdun Competition Position Event Time Wind (m/s) Venue Notes
Ọdun 2019 World Cross Country Championships Ipo Keji Under 20 Race 20:50 Aarhus, Denmark
Ọdun 2019 All African Games Ipo Kẹta 5000 Metres Race 15:37:15 Complexe Sportif Prince Moulay Abdellah, Rabat Morocco
Ọdun 2019 African U20 Championships Ipó akọkọ 3000 Metres Race 9:33:53 Abidjan Cote d'Ivoire

Àwọn Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]