Andry Rajoelina

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Andry Rajoelina
Andry Rajoelina
7th President of Madagascar
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
16 December 2023
Alákóso ÀgbàChristian Ntsay
AsíwájúRichard Ravalomanana (Acting)
In office
19 January 2019 – 10 September 2023
Alákóso ÀgbàChristian Ntsay
AsíwájúRivo Rakotovao (Acting)
Arọ́pòChristian Ntsay (Acting)
In office
17 March 2009 – 25 January 2014
Alákóso ÀgbàMonja Roindefo
Eugène Mangalaza
Cécile Manorohanta (Acting)
Albert Camille Vital
Omer Beriziky
AsíwájúMarc Ravalomanana
Arọ́pòHery Rajaonarimampianina
President of the High Transitional Authority of Madagascar
In office
17 March 2009 – 25 January 2014
Alákóso ÀgbàMonja Roindefo
Eugène Mangalaza
Cécile Manorohanta (Acting)
Albert Camille Vital
Omer Beriziky
AsíwájúOffice established
Arọ́pòOffice abolished
51st Mayor of Antananarivo
In office
12 December 2007 – 3 February 2009
AsíwájúHery Rafalimanana
Arọ́pòGuy Randrianarisoa (Acting)
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí30 Oṣù Kàrún 1974 (1974-05-30) (ọmọ ọdún 49)
Antsirabe, Madagascar
Ọmọorílẹ̀-èdèMalagasy
Ẹgbẹ́ olóṣèlúYoung Malagasies Determined
(Àwọn) olólùfẹ́Mialy Rajoelina née Razakandisa (m. 2000)
Àwọn ọmọ3
ResidenceIavoloha Palace
Websitewww.andry-rajoelina.org

Andry Nirina Rajoelina (ojoibi May 30, 1974)[2] je omo Malagasi oloselu ati onisowo to ni redio ati telifisan.[3] Rajoelina setuka ileasofin, o paro awon adajo ile ejo giga, o si bura funrare bi olori orile-ede igbepada ile Madagascar ni March 21, 2009, leyin igba ti awon ologun ti yan si ipo yi leyin jagidijagan oloselu to sele i 2009.[4] Rajoelina lo je Baale ilu Antananarivo, to je oluilu Madagascar, lati December 2007 de February 2009.[5]



Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]