Aqualtune

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Aqualtune Ezgondidu Mahamud da Silva Santos
Issue
Ganga Zumba

Gana Zona Sabina

House Kongo
Born Kingdom of Kongo

Aqualtune Ezgondidu Mahamud da Silva Santos (fl. 1665) jẹ́ Ọmọ obìnrin tí Ọba kàn tí wọn kò mọ orúkọ rẹ ní ìlú Manikongo. Gẹ́gẹ́ bí àṣà, ó jẹ́ Ìyá Ganga Zumba ati ìyá tí ó bí ìyá Zumbi.[1].

Ni ọdún 1665, Aqualtune jẹ́ olórí ọmọ ogun ẹgbẹẹgbẹrun ọkunrin ati obinrin fún Kongo lọsí Ogun Mbwila, níbití ó tí ṣẹ́gun àwọn ọ̀ta rẹ̀.[1][2] Nígbà èyí, wọ́n gbe lọ sí Port ti Recife], ilé-ìtàjà àti ilé iṣé ọlọ ṣúgà. Wọ́n ra gẹ́gẹ́ bí ẹrú, lẹ́yin náà wọ́n tún ta si ọlọ kan ni Porto Calvo, ní bẹ̀ẹ́ ni ó ti lóyún.[3]Lẹ́yìn tí ó bọ́ ní oko ẹrú yìí, ni ó dé Palmares ní quilombo. Ó dì olórí àti Adarí Subupuialra ni quilombo, èyí tí ó wà ní apa àríwá oòrùn agbègbè kàn ní Palmares. Ó bí ọmọ ọkùnrin méjì, tí wọ́n ń jẹ́ Gangan Zumba àti Gan Sónà, èyí tí àwọn náà padà di Adarí àti olórí ìlú Palmares. Ọmọ rẹ Sabina ló bí Zumbi. Lèyìn gbogbo èyí, a kò mọ ohun tí ó padà gbẹyin ìgbésí ayé àti àyàǹmọ́ rẹ, òkú ikú àràmàdà ní ọdún 1675.[4]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 da Costa, Maria Suely. "REPRESENTAÇÕES DE LUTA E RESISTÊNCIA FEMININA NA POESIA POPULAR" (PDF). III CONEDU Congresso Nacional De Educacao (in Èdè Pọtogí). Universidade Estadual da Paraíba. Archived from the original (PDF) on September 28, 2017. Retrieved May 2, 2018.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. Schwarz-Bart, Simone; Schwarz-Bart, André (2001). In Praise of Black Women: Heroines of the slavery era. Univ of Wisconsin Press. pp. 7–9. ISBN 9780299172602. https://books.google.com/books?id=C5AfcnGEu-QC. 
  3. "The story of the Kongo princess who led 10,000 men into battle and was later enslaved by the Portuguese". Face2Face Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-06-29. Retrieved 2020-10-08. 
  4. Casoy, Julio (2009-02-07). "BLACK HISTORY MONTH: BLACK HEROINES, PART 2: AQUALTUNE: AN ENSLAVED CONGO PRINCESS". BEAUTIFUL, ALSO, ARE THE SOULS OF MY BLACK SISTERS (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-10-08. 

Àdàkọ:Africa-royal-stub