Ashley Battle

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ashley Battle
Free agent
Forward
Personal information
BornOṣù Kàrún 31, 1982 (1982-05-31) (ọmọ ọdún 41)
NationalityAmerican
Listed height6 ft 0 in (1.83 m)
Listed weight170 lb (77 kg)
Career information
High schoolLinsly School
(Wheeling, West Virginia)
CollegeUConn (2000–2005)
NBA draft2005 / Round: 2 / Pick: 25k overall
Selected by the Seattle Storm
Career history
2005Seattle Storm
2006–2009New York Liberty
2010San Antonio Silver Stars

Ashley Battle ti won bi ni ojo kokanlelogbon osu karun un odun 1982, jẹ akosemose agba boolu alapere. Eni ti o dara po mo iko agba boolu alapere Seattle Storm ọdun 2005, o bawon gba ifesewonse meji ki o to di pe won yọkuro. O wa darapo mo New York Liberty fun idije saa 2006 titi di 2009.. O bawon kopa ninu idije ti boolu alapere awon obinrin ti ile-eko agba ti University of Connecticut [1].

Awọn itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Wire, Celtics (2023-03-18). "Ashley Battle's journey from UConn standout to WNBA star to Boston Celtics scout". Celtics Wire. Retrieved 2023-04-15.