Bhumibol Adulyadej

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Bhumibol Adulyadej
Reign 9 June 1946 – 13 october 2016
Coronation 5 May 1950
Predecessor Ananda Mahidol
Heir apparent Maha Vajiralongkorn
Prime Ministers
Spouse Sirikit Kitiyakara
(Since 28 April 1950)
Issue
Princess Ubolratana Rajakanya
HRH Crown Prince Maha Vajiralongkorn
HRH Princess Maha Chakri Sirindhorn
HRH Princess Chulabhorn Walailak
House House of Mahidol
Chakri Dynasty
Father Mahidol Adulyadej, Prince of Songkla
Mother Srinagarindra
Signature
Religion Theravada Buddhism

Bhumibol Adulyadej (Royal Institute: Phumiphon Adunyadet; Tháí: ภูมิพลอดุลยเดช, IPA: [pʰūːmípʰōn àdūnjādèːt];) (bíi ní Ọjọ́ karún Oṣù kejìlá Ọdún 1927 - 13 october 2016) jẹ́ Ọba ní ilẹ̀ Thailand. Wọ́n mọ̀ọ́ sí "eni Olokiki" (Thai: มหาราช, Maharaja), wọ̀n tún mọ̀ọ́ bi Rama Ekesan. Ó ti wà lórí ìtẹ́ lati Ọjọ́ kẹsán Oṣù kẹfà Ọdún 1946, ohun ni ọba tó pẹ́ jùlo láyé lọ́wọ́lọ́wọ àti ọba to wà lórí ìtẹ́ jùlọ]] nínú ̀itàn Thailand.[1]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "A Royal Occasion speeches". Worldhop.com Journal. 1996. Archived from the original on 2006-05-12. Retrieved 2006-07-05.