Birhan Dagne

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Birhan Dagne ni a bini ọjọ kẹjọ, óṣu April, ọdun 1978 jẹ elere sisa lóbinrin jẹ ọmọ bibi ilẹ Ethiopia ṣugbọn to gbe ni ilẹ British . Arabinrin naa da lori ere sisa ti ọna jinjin[1][2].

Àṣèyọri[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Dagne kopa ninu idije agbaye junior ti IAAF ti ọju ọna ni metres ti ẹgbẹrun mẹta ati metres ti ẹgbẹrun mẹwa[3]. Birhan ṣoju fun Britain to si kopa ninu idije agbaye ti IAAF ni ọdun 1999[4]. Ni ọdun 2004, Dagne kopa ninu Marathon ti London larin iṣẹju aya ẹyọkan[5].

Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Birhan Dagne Profile
  2. Dagne Profile
  3. IAAF
  4. Great Britain Marathon
  5. London Marathon