CERN

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Coordinates: 46°14′03″N 6°03′10″E / 46.23417°N 6.05278°E / 46.23417; 6.05278

European Organization
for Nuclear Research
Organisation européenne
pour la recherche nucléaire

Àwọn orílẹ̀-èdè ọmọẹgbẹ́
Ìdásílẹ̀29 September 1954[1]
IbùjókòóGeneva, Switzerland
Ọmọẹgbẹ́Àwọn orílẹ̀-èdè ọmọẹgbẹ́ 21 àti abẹ̀wò 7
Olùdarí ÀgbàFabiola Gianotti
Websitecern.ch
The 12 founding member states of CERN in 1954 a[›] (map borders from 1989)
54 years after its foundation, membership to CERN increased to 20 states, 18 of which are also EU members in 2010

CERN tàbí European Organization for Nuclear Research (Faransé: Organisation européenne pour la recherche nucléaire), lasan bi CERN tabi Cern (play /ˈsɝn/; ìpè Faransé: ​[sɛʁn]; e wo Ìtàn) jẹ́ àgbájọ akáríayé tí iṣẹ́ rẹ̀ ni láti bòjúsí ìṣeṣẹ́ ilé-àdánwò físíksì eruku tóbijùlọ lágbàáyé, tó wà ní àríwáìwọ̀òrùn àdúgbò Geneva ní ẹ̀bá bodè Fránsì àti Swítsàlandì (46°14′3″N 6°3′19″E / 46.23417°N 6.05528°E / 46.23417; 6.05528). Ó jé dídásílẹ̀ ní 1954, àgbájọ náà ní orílẹ̀-èdè ọmọẹgbẹ́ Europe 20.



Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named foundation