Chuba Okadigbo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Chuba Okadigbo
President of the Nigerian Senate
In office
1999–2000
AsíwájúEvan Enwerem
Arọ́pòPius Anyim
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1941-12-17)Oṣù Kejìlá 17, 1941
Ipinle Anambra, Nigeria
AláìsíSeptember 25, 2003(2003-09-25) (ọmọ ọdún 61)
Abuja, Nigeria
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAll Nigeria People's Party

Chuba Okadigbo (17 December, 1941 - 25 September, 2003) je oloselu omo ile Naijiria lati eya Igbo ti a bi ni odun 1941 ti o si ku ni odun 2003. Okadigbo je Aare awon Alagba ile Igbimo Asofin Naijiria lati 1999 titi de 2000.



Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]