Owóníná

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Currency)
Owo wewe

Owóníná le je ohun ti won fi n se kara-kata ni awujo, ilu, ipinle tabi orile-ede kan fun apere naira Nàìjíríà tabi owo wewe ati owo odidi owo ohun ti won je apa didimu ipese owo orile-ede kan. Apa keji ipese owo je awon ti won je fifipamo si ile-ifowopamo