Dàmáskù

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Damascus)
Damascus

دِمَشق Dimashq
[[File:Damsacus infobox2.jpg
|280px|Damascus City landmarks]]
Official seal of Damascus
Seal
Nickname(s): 
(Madīnatu 'l-Yāsmīn) City of Jasmin
CountrySyria
GovernoratesDamascus Governorate, Capital City
Government
 • GovernorBishr Al Sabban
Area
 • City105 km2 (41 sq mi)
 • Urban
77 km2 (30 sq mi)
Elevation
680 m (2,230 ft)
Population
 (2009 est.[1])
 • City1,711,000
Time zoneUTC+2 (EET)
 • Summer (DST)UTC+3 (EEST)
Area code(s)Country code: 963, City code: 11
DemonymDamascene
WebsiteDamascus Governorate
Sources: Damascus city area [2]

Damascus (Lárúbáwá: دِمَشقDimashq), ni Siria won unpe ni Al Sham (Lárúbáwá: الشامAl Shām), ati bi Ilu Jasmine (Lárúbáwá: مدينة الياسمينMadīnatu 'i Yāsmīn), ni oluilu ati ilu keji totobijulo ni Síríà ati ikan ninu awon igberiko 14 ni orile-ede na. Igberiko Damasku ni gomina bi olori toje yiyansipo latowo Alakoso Oro Abele. Damasku je gbangan asa ati esin pataki ni Lẹ̀fántì. Ilu na ni idiye olugbe 1,711,000 (idiye 2009).[1]


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 Central Bureau Of Statistics in Syria: Chapter 2: Population & Demographic Indicators Table 3: Estimates of Population actually living in Syria in 31 December 2009 by Mohafazat and sex (in thousands)
  2. Albaath.news statement by the governor of Damascus, Syria (Lárúbáwá), April 2010