David Àlàbá

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
David Àlàbá
Personal information
OrúkọDavid Olatukunbo Alaba
Ọjọ́ ìbí24 Oṣù Kẹfà 1992 (1992-06-24) (ọmọ ọdún 31)[1]
Ibi ọjọ́ibíVienna, Austria
Ìga1.80 m [2]
Playing positionDefender
Midfielder
Club information
Current clubBayern Munich
Number27
Youth career
2001–2002SV Aspern
2002–2008Austria Wien
2008–2009Bayern Munich
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
2009–2010Bayern Munich II33(1)
2010–Bayern Munich233(20)
20111899 Hoffenheim (loan)17(2)
National team
2007–2009Austria U1720(5)
2010Austria U19[3]5(1)
2009–2010Austria U215(0)
2009–Austria72(14)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 16:23, 21 December 2019 (UTC).

† Appearances (Goals).

‡ National team caps and goals correct as of 21:55, 16 November 2019 (UTC)

David Ọlátòkunbọ̀ Àlàbá tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kẹfà ọdún 1992 jẹ́ ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ṣùgbọ́n tí ó di ọmọ orílẹ̀ èdè Austria, tí ó sìn ń ṣojú orílẹ̀ èdè náà gẹ́gẹ́ bí agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá. Ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Bayern Munich ní o ti ń gba bọ́ọ̀lù jẹun.[4]

Gẹ́gẹ́ bí agbábọ́ọ̀lù tó tó gbangba sùn lọ́yẹ́, ó fẹ́ẹ̀ jẹ́ pé kò sí àyè tí kò lè gbá láàárín gbùngbùn àti ayé ìdáàbòbò ilé.

Gẹ́gẹ́ bí Agbábọ́ọ̀lù, Àlàbá tí gba bọ́ọ̀lù fún ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Bayern Munich nígbà àádọ́ta-lé-lọ́ọ̀ọ́dúnrún, bẹ́ẹ̀ ló ti bá wọn gba ife ẹ̀yẹ lọ́pọ̀ yanturu. Nínú ìtàn, òun ni agbábọ́ọ̀lù tí ó kéré jùlọ fún ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù àgbà fún orílẹ̀ èdè Austria, nígbà tí ó dára pọ̀ mọ́ ikọ̀ náà lọ́dún 2009 nígbà tí ó wà lọ́mọ ọdún mẹ́tàdínlógún.

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "FIFA Club World Cup Morocco 2013: List of Players" (PDF). FIFA. 7 December 2013. p. 5. Archived from the original on 24 December 2018. https://web.archive.org/web/20181224185413/http://www.fifadata.com/document/FCWC/2013/pdf/FCWC_2013_SquadLists.pdf. Retrieved 8 December 2013. 
  2. "David Alaba - Player Profile - Football". Eurosport. 2021-02-12. Retrieved 2021-08-14. 
  3. "Heraf nominiert Kader für U19-EM! 18 Spieler – von Alaba bis Weimann" (in German). oefb.at. Archived from the original on 23 October 2014. Retrieved 23 April 2014. 
  4. "10 things on Bayern Munich's David Alaba". bundesliga.com - the official Bundesliga website. Retrieved 2021-08-14. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]