Degitu Azimeraw

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Degitu Azimeraw
Òrọ̀ ẹni
Ọmọorílẹ̀-èdèEthiopian
Ọjọ́ìbí24 Oṣù Kínní 1999 (1999-01-24) (ọmọ ọdún 25)
Sport
Orílẹ̀-èdèEthiopia
Erẹ́ìdárayáSport of athletics
Event(s)Long-distance running
TeamNN Running Team

Degitu Azimeraw Asires ni a bini ọjọ kẹrin leelogun, óṣu January ni ọdun 1999 jẹ elere sisa lóbinrin ti ọna jinjin órilẹ ede Ethiopia[1][2]

Àṣèyọri[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ni ọdun 2019, Degitu kopa ninu Marathon ti Amsterdam nibi to ti gbe ipo akọkọ pẹlu akọsilẹ ti 2:19:26[3][4]. Ni ọdun 2019, Arabinrin naa kopa ninu ere ilẹ Afirica ti idaji Marathon nibi to ti pari pẹlu ipo kèji pẹlu akọsilẹ ti 1:10:31[5]. Ni ọdun 2021, Degitu kopa ninu Marathon ti ilẹ London nibi to ti pari pẹlu ipo keji pẹlu akọsilẹ ti 02:17:58.

Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Degitu AZIMERAW Profile
  2. Personal Bests
  3. Degitu Azimeraw Breaks Amsterdam Marathon Course Record With 2:19:26 On Her Debut
  4. Amsterdam Marathon
  5. 22019 African Games – Athletics – Results Book" (PDF)