Edgar Lungu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Edgar Lungu
Aare ile Sambia 6k
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
25 January 2015
Vice PresidentInonge Wina
AsíwájúGuy Scott (Acting President) Michael Sata (President)
Alakoso Eto Abo ile Sambia
In office
24 December 2013 – 25 osu kinin 2015
ÀàrẹMichael Sata
Guy Scott
AsíwájúGeoffrey Bwalya Mwamba
Arọ́pòDavies Chama
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí11 Oṣù Kọkànlá 1956 (1956-11-11) (ọmọ ọdún 67)
Ndola, Northern Rhodesia (present-day Zambia)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúUnited Party for National Development
Patriotic Front (current)
(Àwọn) olólùfẹ́
Esther Lungu
(m. 1986)
Àwọn ọmọ6
Alma materUniversity of Zambia

Edgar Chagwa Lungu (ojoibi 11 November 1956) je oloselu ati ohun ni Aare ile Sambia lowolowo lati January 2015.[1][2] Labe Aare Michael Sata, Lungu lo je alakoso fun idajo ati alakoso fun eto abo. Leyin iku ojiji Aare Sata ni October 2014, Lungu je gbigba bi enialedinibo fun egbe oselu Patriotic Front.

O padanu idibo Alakoso 2021 si alatako igba pipẹ Hakainde Hichilema.



Awon Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. https://www.bbc.com/news/world-africa-37086365 | Zambia's President Edgar Lungu declared election winner - BBC News
  2. https://www.bbc.com/news/world-africa-30970952 | Zambia Defence Minister Lungu wins presidential election - BBC News