Egbo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Egbo jẹ́ oúnjẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Egbo jẹ́ oúnjẹ ilẹ̀ Nàìjíríà tó gbajúgbajà ní apá Gúúsù mọ́ Ìwọ̀-oòrùn pàápàá láàárín àwọn ará Ìbàdàn. Láti ara àgbàdo gbígbẹ tí wọ́n sè títí tó ma fi rọ̀ ni wọ́n ti ń ṣẹ̀dá oúnjẹ yìí.[1][2]

Lápapọ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Òhun la tún mọ̀ sí àsáró alágbàdo, Egbo tún súnmọ́ óótímiilì. Nígbà tí a bá jẹ́ pẹ̀lú ọbẹ̀ ata, ẹ̀wà àti ẹ̀fọ́ a mọ̀ ọ́ sí ororo robo.[3]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Foodie corner: I can eat beans seven days a week– Ayo Mogaji". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-10-12. Retrieved 2022-06-29. 
  2. "EJPAU 2005. Abulude F. , Ojo M. DEVELOPMENT AND CHEMICAL EVALUATION OF “EGBO” FORTIFIED WITH LEGUME SEEDS". www.ejpau.media.pl. Retrieved 2022-06-29. 
  3. "Try Egbo with beans". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-07-21. Retrieved 2022-06-29.