Eko FM

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Eko FM
CityLagos
FrequencyÀdàkọ:Frequency
First air date1997 (1997)
Sister stationsRadio Lagos
Websiteekofm.lagosstate.gov.ng

A dá Eko FM sílẹ̀ ní ọdún 1997 gẹ́gẹ́ Ẹ̀ka Radio Lagos . [1]

A dá Eko FM sílẹ̀ lati má gbé ìròyìn jáde fún àwọn ẹ̀yà Yoruba .

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ awọn ara ilu Eko ni ó gbarale ìkànnì yii láti máa mọ bí nǹkan ṣe ń lọ ní agbègbè wọn, gẹ́gẹ́ bi o ṣe n gbé ìròyìn jáde ni ede Gẹẹsi ati awọn èdè local .

Ìwádìí ìjọba ṣe pàtàkì, wọ́n sì ń gbé àwọn ìròyìn tí ó ṣe pàtàkì fún àwọn ará ìlú

Olùdarí Àgbà lọ́wọ́ lọ́wọ́ ní Eko FM 89.7 ni Ọ̀gbẹ́ni Ọlajide Isiaka Lawal.

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. World Radio Tv Handbook. https://books.google.com/books?id=-KY9AQAAIAAJ&q=Eko+89.7+FM+Radio+Lagos.