Farooq Kperogi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Farooq Kperogi
Kperogi in 2021
BornMarch 30, 1973
Baruten, Kwara State, Nigeria
InstitutionsKennesaw State University
Alma materGeorgia State University (Ph.D)
University of Louisiana at Lafayette (M.Sc)
Bayero University (B.A)
Doctoral advisorMichael L. Bruner

Farooq Adamu Kperogi a bi ní ọdún 1973, ó jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ọmọ Nàìjíríà àti Amẹ́ríkà, akọ̀wé, (born 1973), media scholar(ọ̀mọ̀wé ìgbóhùngbáwòrán sáfẹ́fẹ́), akọ̀ròyìn, bílọ́gà àti ajìjàgbara. Ó jẹ́ afìròyìn léde àti aṣàtúnṣe ìròyìn ní ọ̀pọ̀ iwé ìròyìn ilẹ̀ Nàìjíríà tí ó fi mọ́ Daily Trust, Daily Triumph àti New Nigerian.[1][2]

Ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí i aṣèwádìí ní ẹ̀ka ìwádìí àti ìbánisọ̀rọ̀ tí ààrẹ ní ìgbà ìṣèjọba Olusegun Obasanjo, tí ó sì kọ́ ṣíṣẹ ìròyìn àti sísọ̀ ìròyìn ní Ahmadu Bello University àti Kaduna Polytechnic.

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ Ìgbé ayé àti Ẹ̀kọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A bí Kperogi ní ọdún 1973 ní Okuta, Baruten tí ń ṣe agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ìpínlè Kwara, ní Nàìjíríà, ó sì jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Bariba (Baatonu) people.[3] Ó lọ sí Bayero University láàárín1993 àti 1997, ní bi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní mass communication. Ó sì ní ìwé ẹ̀rí nínú communication ìyẹn master's degreeUniversity of Louisiana at Lafayette àti Ph.D. ní Georgia State University ní United States ní ọdún 2011.[4]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Renowned Nigerian columnist, university teacher, Farooq Kperogi, promoted professor" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-03-26. Retrieved 2021-12-18. 
  2. "Farooq Kperogi | Kennesaw State University - Academia.edu". kennesaw.academia.edu. Retrieved 2021-12-18. 
  3. "Kperogi: The Man Who Redefined Grammar Column Writing in Nigeria". jarushub.com. JarusHub. Archived from the original on 6 October 2017. Retrieved 6 October 2017. 
  4. "About me". farooqkperogi.com. Farooq A. Kperogi. Retrieved 6 October 2017.