Fatuma Issa Maonyo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

 

Fatuma Maonyo
Personal information
OrúkọFatuma Issa Maonyo
Ọjọ́ ìbíọjọ́ kẹ̀sán osù Kẹrin ọdún 1995
Ibi ọjọ́ibíTanzania
Playing positionOlùgbèjà
Club information
Current clubSimba Queens
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
Simba Queens
National team
Tanzania
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 2 March 2022. † Appearances (Goals).

Fatuma Issa Maonyo tí a bí ní ọjọ́ kẹ̀sán osù Kẹrin ọdún 1995 jẹ́ ogbóǹtarìgì agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀-ède Tanzania tí ó ṣeré ipò olùgbèjà lórí pápá fún Simba Queens àti ẹgbẹ́ <a href="./Boolu-afesegba" rel="mw:WikiLink">agbábọ́ọ̀lù</a> obìnrin Tanzania .

Isẹ́ Òkè-òkun[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní Oṣù Keje ọdún 2018, Maonyo borí ní bi ìdíje CECAFA Women's Championship ti ọdún 2018 pẹ̀lú Tanzania lẹ́hìn tí ó ṣẹ́gun Etiopia pẹ̀lú àmì ayò mẹ́rin si ọ̀kan (4-1) ní bi ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ ìkẹhìn wọn.

Àwọn ọlá[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Asiwaju Awọn Obirin CECAFA : 2018
  • Oṣere asiwaju Awọn Obirin ti CECAFA ti Idije : 2018

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]