Florence Masebe

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Florence Masebe
Ọjọ́ìbí14 Oṣù Kọkànlá 1972 (1972-11-14) (ọmọ ọdún 51)
South Africa
Orílẹ̀-èdèSouth African
Iṣẹ́
  • actress
Gbajúmọ̀ fúnMuvhango

Florence Masebe (bíi ni ọjọ́ kerìnlélógún oṣù kọkànlá ọdún 1972) jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà tí ó gbajúmọ̀ fún ipá tí ó kó nínú eré Muvhango.[1][2][3] Ó gbà àmì ẹ̀yẹ òṣèré bìnrin to dára jù láti ọ̀dọ̀ Africa Movie Award nibi ayeye kẹsàn-án tí African Movie Academy Awards.

Àṣàyàn àwọn eré tí ó tí se[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Morwalela
  • 7 de Laan Afrikaans
  • Scandal
  • Task Force
  • Soul City
  • Elelwani
  • Ring Of Lies

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Florence Masebe highlights on-set racism of Mzansi Magic soapie". enca.com. Archived from the original on 28 July 2019. Retrieved 17 June 2016. 
  2. "Florence Masebe". tvsa.co.za. 
  3. "Florence Masebe". tvsa.co.za. Retrieved 17 June 2016.