Florence Seriki

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Florence Seriki
Ọjọ́ìbí(1963-08-16)16 Oṣù Kẹjọ 1963
Aláìsí3 March 2017(2017-03-03) (ọmọ ọdún 53)
Ilé ìwòsàn Yunifásitì Ìpínlẹ̀ Èkó
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Iṣẹ́Ònímọ̀ ẹ̀rọ
Notable workOmatek Computers

Florence Seriki MFR (tí a bí ní ọjọ́ kẹríndínlógún oṣù kẹjọ ọdún 1963 tí ó sì fi ayé sílẹ̀ ní ọjọ́ kẹta oṣù kẹta ọdún 2017) jẹ́ olùdásìlẹ̀ àti adarí ilé-isé Omatek Ventures Plc.[1], ilé-isé Nàìjíríà àkọ́kọ́ ní Áfríkà láti ṣe èrọ Kònpútà àti àwọn ẹ̀yà ara Kònpútà.[2]

Ìpìlẹ̀ ayé àti Ẹ̀kọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Seriki ní Ìpínlẹ̀ Èkó ṣùgbọ́n bàbá rẹ̀ jẹ́ ọmọ Ìpínlẹ̀ Delta.[3] Ó lọ ilé-ìwé Sẹ́kọ́ndírì ní Reagan Memorial Baptist Secondary school, Sabo, Yaba láàrin ọdún 1975 àti 1980 ó sì tẹ ẹ̀kọ́ rẹ̀ síwájú ní Federal School of Science, Ẹ̀kọ́. Ó gba àmì-ẹ̀yẹ Bachelors of Science ní Yunifásitì Ilé-Ifè(tí àwọn ènìyàn wá padà mọ̀ sí Yunifásítì Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀, Ile-Ife).[4]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Omatek founder, Florence Seriki, dies at 54". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 6 March 2017. Retrieved 2020-03-09. 
  2. Fadoju, Tobiloba (2017-03-06). "Omatek founder and CEO, Florence Seriki has passed on". Techpoint Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-08-24. 
  3. "Florence Seriki, Omatek Computer's founder is dead". guardian.ng. 6 March 2017. Retrieved 2020-03-09. 
  4. "Florence Seriki: The Woman Entrepreneur Who Built a N3 Billion Tech Company". The Website for African Entrepreneurs (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-09-28. Retrieved 2020-03-09.