Foonu alagbeka

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Foonu alagbekatelifoonu alagbeka jé óun tosé Pataki pupo tiósì me anfaani papa julo latilo fun rirakata pelu awon oun ribiribi imiran tonse funwa lati mu igbesi aiye rorun funwa. Motorola ni ilé-ise tí o koko sé foonu alagbeka ní odun 1973 [1]. La ti igba na, orisirisi foonu alagbeka tí wa kaka kiri lopolopo. ni odun 1989, Motorola se foonu alagbeka ti o le gba àpò aso [2] ni odun 1992, IBM se foonu alafowoteloju àkókó [3]. iyato na ti deba àwon isé tí foonu alagbeka le se, foonu alagbeka tí se fi wo filmu, gbó orin, ka iwe ati bebe lo

Àwon Ìtókasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Goodwin, Richard (2019-04-05). "The History of Mobile Phones From 1973 To 2008: The Cellphones That Made It ALL Happen". Know Your Mobile. Retrieved 2022-02-28. 
  2. Meyers, Justin (2011-05-06). "Watch The Incredible 70-Year Evolution Of The Cell Phone". Business Insider. Retrieved 2022-02-28. 
  3. "Library Guides: Future Phonics: History of Phones". Library Guides at Georgia Southern University. 2017-01-11. Retrieved 2022-02-28.