Freda Linde

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Freda Linde
Ọjọ́ ìbíChristovira Frederika Linde
12 December 1915
Swellendam, Western Cape, South Africa
Ọjọ́ aláìsí7 March 2013(2013-03-07) (ọmọ ọdún 97)
Cape Town, Western Cape, South Africa
Iṣẹ́Journalist, Writer and Translator
ÈdèAfrikaans
Ọmọ orílẹ̀-èdèSouth African
Alma materHoërskool Jan van Riebeeck

Freda Linde (12 December 1915 – 7 March 2013[1] ) jẹ́ òǹkọ̀wé ìwé àwọn ọmọdé àti ògbufọ̀ ti ilẹ̀ South Africa. Èdè Afrikaans ló máa ń lò fún ìwé kíkọ rẹ̀. Ó ti ṣe ògbufọ̀ àwọn ìwé ọmọdé tó ju àádọ́jọ lọ sí èdè Afrikaans, French àti German.[2] Ó gba àmì-ẹ̀yẹ ti C.P. Hoogenhout Award ní ọdún 1964.

Ayé rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ìlú Swellendam ni wọ́n bi sí, ó sì ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí i akọ̀ròyìn àti olóòtú títí wọ ọdún 1960. Láti ọdún 1960 wọ 1963, ó jẹ́ olóòtú ilé-iṣẹ́ atẹ̀wétà HAUM, àti láti ọdún 1964 wọ ọdún 1971 ó jẹ́ olóòtú tó ń ṣiṣẹ́ lórí àwon ìwé lítíréṣọ̀ ọmọdé ní John Malherbe publishers. Ó fẹ̀yìn tì láti ṣiṣẹ́ ìwé-kíko ní pẹrẹu ní ọdún 1972.[3]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Terblanche, Erica. "Freda Linde (1915 - 2013)" (in Afrikaans). Archived from the original on 10 July 2013. Retrieved 5 August 2013.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. Freda Linde
  3. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named StellenBosch2