Fyodor Dostoyevsky

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Fyodor Dostoevsky
Iṣẹ́Novelist
Genresuspense, literary fiction
Notable worksCrime and Punishment
The Idiot
The Brothers Karamazov
The Possessed

Signature

Fyodor Mikhaylovich Dostoyevsky (Rọ́síà: Фёдор Миха́йлович Достое́вский, Fëdor Mihajlovič Dostoevskij, pípè [ˈfʲodər mʲɪˈxajləvʲɪtɕ dəstɐˈjɛfskʲɪj]  ( listen)),[4] nigba miran bi Dostoevsky, Dostoievsky, Dostojevskij, Dostoevski, Dostojevski tabi Dostoevskij (11 November [O.S. 30 October] 1821 – 9 February [O.S. 29 January] 1881) je olukowe ati alaroko omo Rosia, to gbajumo fun awon iwe itan aroko re Iwa odaran ati Ijiya ati Awon Arakunrin Karamazov.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]