Giordano Bruno
Giordano Bruno | |
---|---|
Orúkọ | Giordano Bruno |
Ìbí | 1548 (date not known) Nola, Kingdom of Naples, in present-day Italy |
Aláìsí | February 17, 1600 (ọmọ ọdún 51–52) Rome, Papal States, in present-day Italy |
Ìgbà | Renaissance philosophy |
Agbègbè | Europe |
Ìjẹlógún gangan | Philosophy, Cosmology, and Memory |
Giordano Bruno (1548 – February 17, 1600), oruko abiso Filippo Bruno, je ara Italia elesin Dominiki, amoye, onimomathimatiki ati atorawo, to gbajumo bi elegbe ijeailopin agbalaaye. Awon irojinle oro-ida aye re koja afijuwe ti Koperniku lo nipa pe o pe Òrùn bi ikan ninu awon ohun agbarajo ojuorun alainiye ti won unda lo kiri: ohunni ara Europe akoko to setumo agbalaaye bi ohun ajapo nibi ti awon irawo ti a unri lale ri bakanna bi Orun. O je siseku pa pelu ijona lowo awon alase i 1600 leyin ti Ile Iwadi Romu dalebi esun ailesin to je aibofinmu nigbamo. Leyi iku re o gbajumo gidi; ni orundun 19k ati ibere orundun 20k, awon olutuwo ti won gbe awon igbagbo alatorawo re wo gba bi akoni fun ironu ominira ati awon erookan sayensi odeoni.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |