James Joyce

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Half-length portrait of man in his thirties. He looks to his right so that his face is in profile. He has a mustache, a thin beard, and medium-length hair slicked back, and wears a pince-nez and a plain dark greatcoat, looking vaguely like a Russian revolutionary.
Joyce in Zürich, c. 1918

James Augustine Aloysius Joyce (2 February 1882 – 13 January 1941) je olukowe ati ako-ewi omo Irelandi, to je gbigba gege bi ikan ninu awon olukowe to ipa julo ni orundun 20. Pelu Marcel Proust, Virginia Woolf, ati awon yioku, Joyce ko ipa pataki ninu igbega itan-aroko odeoni. O gbajumo fun iwe re bi Ulysses (1922) ati Dubliners (1914), A Portrait of the Artist as a Young Man (1916) ati Finnegans Wake (1939).

Dubliners, 1914


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]