Gwendolyn Brooks

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Gwendolyn Brooks
Iṣẹ́Poet
Ọmọ orílẹ̀-èdèUnited States of America
Ìgbà1930-2000
GenrePoetry
Notable worksAnnie Allen
Notable awardsPulitzer Prize for Poetry (1950)
SpouseHenry Blakely (m. 1939)

Gwendolyn Elizabeth Brooks (June 7, 1917 – December 3, 2000) je olukowe omo orile-ede Amerika. Won yan bi Poet Laureate Consultant in Poetry to the Library of Congress in 1985.[1]

Igbesiaye[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Igba ewe[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Gwendolyn Elizabeth Brooks je bibi ni June 7, 1917, ni Topeka, Kansas fun David Anderson Brooks ati Keziah Wims, o je akobi. Iya re je oluko tele ki o to fi se sile lati setoju awon omo re, baba re, to je omo eru to ja ninu Ogun Abele, je asona nitoripe ko ni owo lati losi ile-eko onisegun lati di dokita. Nigbati Brooks di omo ose mefa, won ko lo si Chicago, Illinois, nibi to ti dagba.




Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Poet Laureate Timeline: 1981-1990". Library of Congress. 2008. Retrieved 2008-12-19.