Hyacinth Alia

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Hyacinth Iormem Alia
19th Governor of Benue State
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ́n oṣù karùn-ún ọdún (29/5) 2023
DeputySamuel Ode
AsíwájúSamuel Ortom
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí15 Oṣù Kàrún 1966 (1966-05-15) (ọmọ ọdún 57)
Mbangur, Mbadede, Vandeikya, Ìpínlẹ̀ Benue, Nigeria
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAll Progressives Congress
OccupationPolitician, Catholic priest

Hyacinth Iormem Alia (wọ́n bí lọ́jọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún, oṣù karùn-ún ọdún, 1966) jẹ́ òṣèlú ọmọ Nigeria àti àlùfáà ìjọ Kátólíìkì tí ó di gómìnà Ìpínlẹ̀ Benue láti ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ́n oṣù karùn-ún ọdún 2023.[1][2][3]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "INEC Declares Catholic Priest, Fr Hyacinth Alia Benue Gov-Elect". 20 March 2023. https://www.channelstv.com/2023/03/20/breaking-inec-declares-catholic-priest-fr-hyacinth-alia-benue-gov-elect/amp/. 
  2. Ejekwonyilo, Ameh (20 March 2023). "Catholic priest Hyacinth Alia wins Benue State governorship election". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-03-21. 
  3. "Reverend Father Hyacinth Alia wins Benue guber election". TheCable (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 20 March 2023. Retrieved 2023-03-21.