Ibojì Òkú

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Common Burying Ground and Island Cemetery in Newport, Rhode Island
Old graveyard in Elazig, Turkey
A Muslim cemetery at sunset in Marrakech, Morocco
A cemetery in Kyoto, Japan
Two Colonial era graves in Pemaquid, Maine
Noratus cemetery, a medieval Armenian cemetery with a large number of early khachkars. The cemetery has the largest cluster of khachkars in the
iboji wawu ti ilu Badagry

Ibojì Òkú tàbíItẹ̀ Òkú jẹ́ ibi tí wọ́n ń sin àwọn ènìyàn tí ó ti kú tàbí papò dà sí. Wọ́n ṣẹ̀dá ọ̀rọ̀-orúkọ yíIbojì láti inú( èdè Gíríkì κοιμητήριον, tí ó túmọ̀ sí "ibùsùn") tí ó túmọ̀ sí wípé ìwọ̀nba ilẹ̀ tí wọ́n yà sọ́tọ̀ yí ni wọ́n ṣàdáyanrí fún sín sin àwọn aláìsí sí. Wọ́n sábà ma ń lo àwọn gbólóhùn wọ̀nyí "Ibojì Òkú tàbí Itẹ̀ Òkú", àmọ́ ṣá, nínú èdè Gẹ̀ẹ́sì, Ibojì sábà ma ń jẹ́ apá ilẹ̀ kan tí wọ́n yà sọ́tọ̀ nínú Ilé Ìjọsìn láti máa fi sin àwọn Páítọ̀, Àlùfáà, àti Díkìnì, ìjọ sí. [1][2]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]