Jessica oyelowo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jessica Oyelowo ni ayeye kan
David ati Jessica Oyelowo

Jessica Oyelowo (née Watson; ti a bi ni 1978) je osere ati okorin ti Britain[1]

Iberepepe Aye[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Oruko ti won so ni Jessica Watson ni Ipswich o si dagba si Suffolk, ni England.[1] O losi ile iwe alakobere ti Woodbridge School nigba ti o wa ni kekere. o si je omo egbe National Youth MUsic Theatre .[1]

Ise[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ni odun 2006, oun lo se Detective Sergeant Alex JOnes[1] ni Mayo o si tun wa ninu ere ti won pe ni Murphy's Law ti James Nesbitt na wa nibe, in 2007.[2] O fi ohun re sile lati se Mrs. Equiano (ti oko Mr Equiano naa re si je husband Olaudah Equiano ninu ere Grace Unshackled – The Olaudah Equiano Story, eyi ti o je ere itage ti o maa n waye lori ti won yalo lati Equiano's 1789 autobiography ti a mo si The Interesting Narrative of the Life of Olaudah Equiano. Ti akoko iru re si waye lori BBC 7 ni osu kerin odun 2007.

Igbe Aye[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Oyelowo n gbe ni Tarzana ni San Fernando Valley ni Southern California pelu oko re ti oun naa je osere ti oruko re si n je David Oyelowo. awon meejeji pade nigba ti won lo si London Academy of Music and Dramatic Art.[3][4] Won ni awon omo merin.[3][5][6] Ti won n gbe ni Brighton, England.[4]

Awon meejeji si je kiteeni.[3]

Oyelowo ati oko re je naturalised US citizens ni 20 July 2016.[7][8]

Gege bi o ti je Aya omo Yoruba yi ti o tun je omooba ,[9] Oyelowo ni eto si ki a pe ni Olori. Amo kii saba lo.[citation needed]

Filmography[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Year Title Role Notes
1999 Sleepy Hollow Sarah
2004 Churchill: The Hollywood Years Princess Margaret
2005 It's a Boy! Mary Video short
2009 Big Guy Bear Vendor Short
2010 Alice in Wonderland Woman with Large Poitrine in Red Queen Court
2011 Rahab Rahab Short
2015 Captive Meredith MacKenzie
2016 Nina Nurse
2016 United Kingdom, AA United Kingdom Lady Lilly Canning
2019 Sorry, Not Sorry Abby Short
2020 The Water Man Missus Bakemeyer Also composed and performed several songs

Stage work[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Awon Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 1.2 1.3 "Suffolk actress in crime show". Ipswich Star. March 31, 2006. Archived from the original on April 2, 2015. https://web.archive.org/web/20150402153444/http://www.ipswichstar.co.uk/news/features/suffolk_actress_in_crime_show_1_107596. 
  2. "Be glad he's on your side". BBC. Retrieved 4 October 2007. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  3. 3.0 3.1 3.2 Gilbert, Gerard (February 8, 2013). "Upwardly mobile: David Oyelowo on going from Tooting Bec to Tom Cruise's jet". The Independent. Archived from the originalPaid subscription required on 8 June 2022. Retrieved October 10, 2016.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. 4.0 4.1 "Suffolk actress in crime show". Ipswich Star. March 31, 2006. Archived from the original on April 2, 2015. https://web.archive.org/web/20150402153444/http://www.ipswichstar.co.uk/news/features/suffolk_actress_in_crime_show_1_107596. 
  5. Gilbey, Ryan (1 February 2015). "David Oyelowo: 'No one says to Oliver Stone: white characters AGAIN?'". The Guardian. Retrieved 16 September 2015. 
  6. Mandell, Andrea (10 October 2012). "David Oyelowo comes out of 'Nowhere' to become star". USA Today. Retrieved 16 September 2015. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  7. WENN.com (29 September 2016). "David Oyelowo was inspired to become a citizen after filming Selma". The Oregonian. Archived from the original on 18 November 2018. Retrieved 27 December 2018.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  8. Park, Andrea (24 November 2016). "David Oyelowo on his first Thanksgiving as an American citizen". CBS News. 
  9. "David Oyelowo interview: The Selma actor on being an African prince". Independent.com. Archived from the originalPaid subscription required on 8 June 2022. Retrieved July 27, 2021.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  10. Hickling, Alfred (7 December 2006). "Cyrano de Bergerac". The Guardian. https://www.theguardian.com/stage/2006/dec/07/theatre. 

External links[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]