John Dabiri

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
John O. Dabiri
Dr Dabiri
ÌbíToledo, Ohio
Ará ìlẹ̀United States, Nigeria
PápáAeronautics
Bioengineering
Mechanical engineering
Ilé-ẹ̀kọ́Caltech
Stanford University
Ibi ẹ̀kọ́Princeton University (B.S.E.)
Caltech (Ph.D.)
Doctoral advisorMorteza Gharib
Ó gbajúmọ̀ fúnVortex formation
Reverse engineering of jellyfish
Applications to wind turbines
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síPECASE (2008)
MacArthur Fellow (2010)
Alan T. Waterman Award (2020)

John Oluseun Dabiri[1] jẹ́ ọmọ Naijiria tó tún tan mọ́ ilẹ̀ America. Ó jẹ́ onímọ̀ ẹ̀rọ tó ń rí sí ọkọ̀ òfurufú, òun sì ni ọ̀jọ̀gbọ́n alága ní California Institute of Technology (Caltech).[2] [3]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named google
  2. Dabiri Lab. John Dabiri. Retrieved 27 September 2019.
  3. Biological Propulsion Laboratory Archived 2011-09-03 at the Wayback Machine.. See the People page. Retrieved 23 July 2012.