John Malkovich

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
John Malkovich
Malkovich ní ọdún 2023
Ọjọ́ìbíOṣù Kejìlá 9, 1953 (1953-12-09) (ọmọ ọdún 70)
Christopher, Illinois, U.S.
Iléẹ̀kọ́ gígaWilliam Esper Studio
Iṣẹ́
  • Actor
  • filmmaker
  • theatre director
  • fashion designer
Ìgbà iṣẹ́1976–present
WorksSee filmography
Olólùfẹ́
Glenne Headly
(m. 1982; div. 1988)
Alábàálòpọ̀Nicoletta Peyran (1989–present)
Àwọn ọmọ2

John Malkovich (tí a bí ní ọjọ́ kẹsán oṣù Kejìlá ọdún 1953) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà. Ó ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì-ẹ̀yẹ, àwọn bi Primetime Emmy Award, wọ́n sì ti yán mọ́ àwọn tí ó tó sí àmì-ẹ̀yẹ Academy Awards lémejì, BAFTA Award, Screen Actors Guild Awards, àti àmì ẹyẹ Golden Globe Awards lẹ́meta.

Malkovich bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré gẹ́gẹ́ bi nígbà tí ó darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ Steppenwolf Theatre Company ní Chicago ní ọdún 1976.[1] Àwọn fíìmù tí ó ti ṣeré ni True West (1980), Death of a Salesman (1984), The Caretaker (1986), àti ní Burn This (1987), Places in the Heart (1984), In the Line of Fire (1993), The Killing Fields (1984), Empire of the Sun (1987), Dangerous Liaisons (1988), Of Mice and Men (1992), Con Air (1997), Rounders (1998), Being John Malkovich (1999), Shadow of the Vampire (2000), Ripley's Game (2002), Burn After Reading (2008), and Red (2010). Ó ti ṣe àgbéjáde àwọn fíìmù bi Ghost World (2001), Juno (2007), àti The Perks of Being a Wallflower (2012).

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named Wood