Johnson Jakande Tinubu Park (JJT Park)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Johnson Jakande Tinubu Park jẹ́ ọgbà ìṣèré tí ó wà ní ìtòsí Ikeja, ní ìpínlẹ̀ Èkó (èyí tí a máa ń pè ní Lagos ní èdè Gẹ̀ẹ́sì). Wọ́n ṣe ìdásílẹ̀ ọgbà yìí pẹ̀lú àṣẹ nípasẹ̀ Gómìnà ìpínlẹ̀ Èkó ní Oṣù Kejìlá, Ọdún 2017. Ó jẹ́ ààyè eré ìdárayá tí ó wà láàrín ìsúnmọ́tòsì ọfíísì ti Gómìnà, Lagos State House of Assembly àti State Secretariat.[1][2][3] Ọgbà náà sábà máa ń ṣiṣẹ́ gan-an nígbà tó àkókò àwọn ayẹyẹ, ṣùgbọ́n ní ọjọ́ tí iṣẹ́ ń lọ déédé àti ní ìparí ọ̀sẹ̀, àwọn olùgbé àti púpọ̀ nínú àwọn òṣìṣẹ́ láàrín agbègbè yìí máa ń wọ ọgbà-ìtura yìí láti sinmi àti láti tún ra ṣe.

Àwòrán[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn Ìtọ́ka Sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Photos: Johnson Jakande Tinubu (JJT) Park At Alausa, Ikeja". Vanguard. 13 December 2017. 
  2. Times, Premium (20 May 2021). "Lagosians need relaxation because 'there is a lot of chaos in the land' – LASPARK boss". Premium Times. Retrieved 23 February 2022. 
  3. Ochuko, Rukewve (29 November 2021). "Free Cool Hang Out Spots In Lagos, Nigeria". The Guardian. Retrieved 23 February 2022.