Judith Chime

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Judith Chime
Personal information
Ọjọ́ ìbí20 Oṣù Kàrún 1978 (1978-05-20) (ọmọ ọdún 45)
Ibi ọjọ́ibíLagos, Nigeria
Playing positionGoalkeeper
National team
YearsTeamApps(Gls)
2000Nigeria women's national football team
† Appearances (Goals).

Judith Chime jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 20, óṣu May ni ọdun 1978. Arabirin naa jẹ ẹni ti o ti gba jẹ goalkeeper bọọlu ri fun team apapọ awọn obinrin ilẹ naigiria ti bọọlu[1][2][3][4].

Àṣeyọri[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Judith ti kopa ninu Cup FIFA awọn obinrin agabaye ni ọdun 1999 ati ọlympic ọdun 2000[5][6].

Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. https://guardian.ng/sport/super-falcons-former-star-judith-chime-mobilises-support-for-olympics-eagles-in-atlanta/
  2. https://www.eurosport.com/football/judith-chime_prs414910/person.shtml
  3. https://fbref.com/en/players/5ecd3038/Judith-Chime
  4. https://ng.soccerway.com/players/judith-chime/291463/
  5. https://www.playmakerstats.com/player.php?id=182375&edicao_id=2150
  6. https://www.cafonline.com/news-center/news/remembering-1998-all-conquering-super-falcons