Kókóró (oúnjẹ)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Kokoro jẹ́ oúnjẹ ìbílẹ̀ àwọn Yorùbá Àwọn nnkan tí wọ́n f ṣe é ni àgbàdo, súgà, èlùbọ́ tàbí gàrí gbígbẹ.[1][2][3][4][5]

Ó ṣe é tọ́jú fúngbà pípẹ́ tí a bá gbé e pa mọ́ kúrò níbi tí atẹ́gùn wà. Oríṣi kókóró méjì ni ó wà, àwọn ni kókóró gbẹrẹfu àti aláta.[6]

Lẹ́yìn tí a bá ti da àgbàdo gbẹrẹfu sínú omi gbígbóná, a máa rò ó pọ̀ dáadáa. A máa wá dà á sínú òróró tó gbóná.[7]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "5 Snacks you can only find in Nigeria". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-02-23. Retrieved 2022-06-30. 
  2. "Composition of kokoro". ResearchGate. https://www.researchgate.net/figure/Proximate-composition-of-kokoro-snacks-produced-from-maize-defatted-coconut-flour_tbl1_316502628. 
  3. Uzor-Peters, P. I.; Arisa, N. U.; Lawrence, C. O.; Osondu, N. S.; Adelaja, A. (2017-07-17). "Production of Kokoro with better nutritional content and sensory quality from maize flour". African Journal of Food Science Research 6 (3): 1–4. ISSN 2375-0723. https://www.internationalscholarsjournals.com/abstract/production-of-kokoro-with-better-nutritional-content-and-sensory-quality-from-maize-flour-59610.html. 
  4. Okolie, Pius Ifeanyi; Temitope, Coker Muibat; Okolie, Emilymary Chima; Oke, Emmanuel Kehinde; Agboola, Kudirat Aina; Abayomi, Solomon Olutayo (2022-06-01). "Physiochemical and quality evaluation of kokoro (A Maize-based snack) from blends of yellow maize, fermented AYB and RICE bran flours" (in en). Applied Food Research 2 (1): 100104. doi:10.1016/j.afres.2022.100104. ISSN 2772-5022. https://www.sciencedirect.com/science/article/pii/S2772502222000646. 
  5. "Kokoro". ResearchGate. https://www.researchgate.net/publication/339274686. 
  6. "Maize-based snack: Kokoro". ResearchGate. https://www.researchgate.net/publication/360077290. 
  7. "How To Make Traditional Kokoro Snack". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-04-21. Retrieved 2022-06-30.