Ketia Mbelu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́


Ketia Mbelu
Òrọ̀ ẹni
Ọmọorílẹ̀-èdèOlómìnira Òṣèlú ilẹ̀ Kóngò
Ọjọ́ìbí18 April 2001
Height170cm / 5'7"[1]
Sport
Erẹ́ìdárayáVolleyball

Ketia Mbelu (ọjọ́ ìbí Ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kẹ̀rin, ọdún 2001) jẹ́ éléréìdárayá bọ́ọ̀lù aláfọ̀wọ́gbá ọmọ orílẹ̀-èdè Olómìnira Òṣèlú ilẹ̀ Kóngò tí o n sojú CNSS (DR Congo-D1) ẹ́gbé obìnrin bọ́ọ̀lù aláfọ̀wọ́gbá ti Orílẹ̀-èdè Olómìnira Òṣèlú ilẹ̀ Kóngò.[2][3]

Awon ìdíje tí o ti kópa[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní ọdún 2023, Ketia ati awọn akẹ́gbẹ́ rẹ lọ sojú orílẹ̀-èdè Olómìnira Òṣèlú ilẹ̀ Kóngò níbi ti o gba àmì mẹẹdogun, pelu ìránlọ́wọ́ mẹ́rin láti borí orile-èdè Gabon ti o si mu orile-ede rẹ̀ pegédé fún ìdíje Women's AfroBasket ti ọdún 2023[4][5]

Awọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Ketia Mbelu". FIBA 3x3. Retrieved 2024-04-21. 
  2. "Player Profile". FIBA.basketball. 2001-04-18. Retrieved 2024-04-21. 
  3. "Ketia Mbelu, Basketball Player, News, Stats". Eurobasket LLC. Retrieved 2024-04-21. 
  4. "DR Congo qualify for the 2023 Women's AfroBasket after wins over Gabon". FIBA.basketball. Retrieved 2024-04-21. 
  5. Muhima, Georges Ben (2023-07-27). "Afrobasket : Défaite des Léopards Dames en amical avant le début de la compétition". Kivu Morning Post (in Èdè Faransé). Retrieved 2024-04-21.