Khabonina Qubeka

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Khabonina Qubeka
Ọjọ́ìbíOṣù Kínní 22, 1981 (1981-01-22) (ọmọ ọdún 43)
Orlando West Extension, Soweto
Orílẹ̀-èdèSouth Africa
Orúkọ mírànKhabodacious. Nina
Ẹ̀kọ́Moving Into Dance
Iṣẹ́Actress Dancer
Gbajúmọ̀ fúnIsidingo
Àwọn ọmọ1

Khabonina Qubeka(bíi ni ọjọ́ kẹji lélógún, ọdún 1981[1]) jẹ́ òṣèré, agbóhùnsáfẹ́fẹ́, oníjó[2][3] àti olórin ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà.[4][5][6][7] Ní ọdún 2017, ó gbà àmì ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bí òṣèré bìnrin to dára jù lọ níbi ayẹyẹ Boston International Film Festival Awards, wọn si yàán kalẹ̀ fún ẹ̀bùn òṣèré bìnrin tó dára jù lọ níbi ayẹyẹ Florida Film Festival àti African Movie Academy Awards fun ipa Dora tó kó nínú eré Dora's Peace.[8][9] Ní ọdún 2017, ó kó ipa Nínà Zamdela nínú eré Isindigo. Ó ṣe atọkun fún ètò Fix My Love tí ilé iṣẹ́ Bet gbé kalẹ̀, ó sì gbajúmọ̀ fún ipá Maxine tí ó kó nínú eré The Wild. Gẹ́gẹ́ bíi oníjó, ó ti ṣe atọkun àti adájọ́ fún oríṣiríṣi àwọn ètò ijó bíi Dance Your Butt Off, Step up or Step Out.

Iṣẹ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Qubeka di gbajúmọ̀ fún ipá Doobsie tí ó kó nínú eré Muvhango ni ọdún 2006. Ó ti kopa ninu awọn eré bíi She is King[10] ati Isidingo. Ní ọdún 2017, ó gbà àmì ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bí òṣèré bìnrin to dára jù lọ níbi ayẹyẹ Boston International Film Festival. Ni osu kewaa, ọdun 2017, o se atọkun fun eto ti won se fun awọn oluọ ni South Afrika.[11]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. admin (November 7, 2017). "Khabonina Qubeka". tvsa.co.za. Retrieved November 7, 2017. 
  2. admin (January 4, 2017). "Khabonina Qubeka flaunts her yoga moves in Dubai". channel24.co.za. Retrieved November 7, 2017. 
  3. admin (May 17, 2017). "Khabonina: South Africa’s award-winning leading lady". Brand South Africa. Retrieved 2017-11-30. 
  4. Media, TEAMTalk (5 May 2013). "Qubeka makes Khabodacious waves". The Citizen (South Africa). Retrieved 2019-12-31.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. "'Khabonina With The Cuteness' Talks About That Rap Video". HuffPost UK (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 5 April 2018. Retrieved 31 December 2019.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  6. Komana, Keitumetse (May 30, 2019). "Khabonina takes AfroYoga to Hong Kong". Bedfordview Edenvale News. Retrieved December 31, 2019.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  7. Komana, Keitumetse (30 May 2019). "Khabonina takes AfroYoga to Hong Kong". Bedfordview Edenvale News. Retrieved 31 December 2019.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  8. admin (April 25, 2017). "Khabonina Qubeka's Portrayal Of A Joburg Prostitute Has Won Her Best Indie Actress In The U.S.". Huffington Post. Archived from the original on November 12, 2017. Retrieved November 7, 2017. 
  9. admin (April 20, 2017). "Actress Qubeka bags an international award". Newsday. Retrieved November 7, 2017. 
  10. Herinbi, Helen (September 18, 2017). "Khabonina Qubeka is 'King'". iol.co.za. Retrieved November 7, 2017. 
  11. admin (October 5, 2017). "Khabonina Qubeka on upcoming reality show". ghafla.com. Retrieved November 7, 2017.