Koelliker's glass lizard

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Koelliker's glass lizard
Ipò ìdasí
Ìṣètò onísáyẹ́nsì
Ìjọba:
Ará:
Subphylum:
Ẹgbẹ́:
Ìtò:
Suborder:
Infraorder:
Ìdílé:
Subfamily:
Ìbátan:
Hyalosaurus
Irú:
H. koellikeri
Ìfúnlórúkọ méjì
Hyalosaurus koellikeri
Günther, 1873
Synonyms

Koelliker's glass lizard (Hyalosaurus koellikeri ), ti won sábà ma ń pè ní  Moroccan glass lizard, jẹ́ àwọn ẹ̀yà alángba ti ẹbí Anguidae.[2]

Orísun rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n fi orúkọ rẹ̀ ganga koellikeri, fi dá Albert von Kölliker tí ó jẹ́ onímọ̀ histology ọmọ Swiss lọ́lá.[3]

Ìtòsí ibi tí ó má n wà[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n máa ń rí H. koellikeriAlgeria àti Morocco.[2]

Ibùgbé[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ibi tí  Koelliker's glass lizard ma ń sábà gbé ni àwọn igbó tó móoru, tí koríko pọ̀ sí àti ewéko.[2]

Ipò ìtọ́jú[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ìba igbó jẹ́ maa ń ṣàkóbá fún H. koellikeri.[2]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Ophisaurus koellikeri ". The Reptile Database. www.reptile-database.org.
  2. 2.0 2.1 2.2 2.3 Ineich I, Crochet P-A, Geniez P. 2005.
  3. Beolens B, Watkins M, Grayson M. 2011.

Ìwé àkàsíwájú[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Boulenger GA. 1885. Catalogue of the Lizards in the British Museum (Natural History). Second Edition. Volume II. ... Anguidae ... London: Trustees of the British Museum (Natural History). (Taylor and Francis, printers). xiii + 497 pp. + Plates I-XXIV. (Ophisaurus koellokeri, new combination, p. 283 + Plate XV, figures 2, 2a, 2b).
  • Günther A. 1873. "Description of a new Saurian (Hyalosaurus) allied to Pseudopus ". Ann. Mag. Nat. Hist., Fourth Series 11: 351. ("Hyalosaurus Kœllikeri ", new species).
  • Sindaco R, Jeremčenko VK. 2008. The Reptiles of the Western Palearctic. 1. Annotated Checklist and Distributional Atlas of the Turtles, Crocodiles, Amphisbaenians and Lizards of Europe, North Africa, Middle East and Central Asia. (Monographs of the Societas Herpetologica Italica). Latina, Italy: Edizioni Belvedere. 580 pp. ISBN 978-88-89504-14-7. (Hyalosaurus koellikeri).