Kunle Remi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Kunle remi)
Kunle Remi
Ọjọ́ìbíÒyekúnlé Ọpẹ́yẹmí Ọlúwarẹ̀mí
18 Oṣù Kẹ̀wá 1988 (1988-10-18) (ọmọ ọdún 35)
Gboko, Benue, Nàìjíríà
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Orúkọ mírànKunle Rhemmy
Teslim
Terdo
KR
Iléẹ̀kọ́ gígaFáṣítì Ìbàdàn
New York Film Academy
Iṣẹ́Ọ̀ṣèré
Ìgbà iṣẹ́2010 – Present

Kúnlé Rẹ̀mí (Wọ́n bi ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kẹwàá, ọdún 1988 | Orúkọ ìbí- Oyèkúnlé Ọpẹ́yẹmí Olúwarẹ̀mí) jẹ́ Òṣèré Nàìjíríà , tí wọ́n mọ̀ ọ́ fún àwọn ipa ribiribi rẹ̀ ní Falling,[1] Family ForeverÀdàkọ:Cn and Tinsel. Ó di olókìkí lẹ́hìn ìgbà tí ó borí ìgbà kéjẹ tí wọ́n ṣe Gulder Ultimate Search ní ọdún 2010.[2] Ó parí láti New York Film Academy.[3]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]