Ladji Diakité

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ladji Diakité
لادجي دياكيتي
Ọjọ́ìbíLadji Diakité
Bamako, Mali
Orílẹ̀-èdèMalian
Iléẹ̀kọ́ gígaEcole Normale Supérieure
Iṣẹ́Director, assistant director, costume designer
Ìgbà iṣẹ́1991–present

Ladji Diakité jẹ́ olùdarí eré ọmọ orílẹ̀-èdè Málì. Ó gbajúmọ̀ jùlọ fún dídarí àwọn fíìmù bíi Duel à Dafa àti Fantan Fanga.[1] Yàtò sí dídarí eré, Diakité tún jẹ́ aṣàpẹẹrẹ aṣọ.[2]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Liste films de Ladji Diakité". clapnoir. Retrieved 9 October 2020. 
  2. "Ladji Diakité: Director, Costume designer". MUBI. Retrieved 9 October 2020.