Lagoon Hospitals

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Awọn ile-iwosan Lagoon, jẹ́ ọkàn nínú àwọn ilé-ìwòsàn tí ó tóbi jùlọ ní Nigeria.

Lagoon_Hospital_Gate,_Ikeja

Ìbi ti àwon ilé-ìwòsàn wọn wà[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n dá ilé-ìwòsàn yìí sílẹ̀ ní ọdún 1986 lábẹ́ Ẹgbẹ́ Hygeia, ilé-iṣẹ ìlera yìí ń ṣe ìtọ́jú ọ̀pọ̀lọpọ̀ awọn àìsàn. Ibùgbé mẹ́rin ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ní ilé-ìwòsàn yìí ní ẹ̀ka sí; àwon náà ni: ilé-ìwòsàn Lagoon Apapa, ilé-ìwòsàn Lagoon Ikeja, ilé-ìwòsàn Lagoon Victoria Island ati ilé-ìwòsàn Lagoon Ikoyi. Ilé-ìwòsàn tí Apapa jẹ olú-iléìwòsàn náà. Laipẹ̀, wọ́n tún pẹ̀ka ilé-iṣẹ́ méjì mìíràn ní Adeniyi Jones, Ikeja ati Lagoon Specialist Suites ni Victoria Island, apapọ gbogbo rè jé mẹfa.

Awọn iṣẹlẹ pataki[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Awọn ile-iwosan Lagoon ti ṣe aṣáájú-ọnà nínú ilọsiwaju ètò ilera ni Naijiria. Ile-iwosan Lagoon jé ile-iwosan aladani akọkọ ni orilẹ-ede Nàìjíríà TiVo koko se abe òkan ní aseyori. Àwon egbé omosedaju Dokita ní Nàìjirià ni o se abe náà.

Àríyànjiyàn nipa ile ìwòsàn yìí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwon ènìyàn bèrè si un soro òdì si lagoon hospital nígbà ti òrò kan kókó jáde pé “wòn pan dadan fun àwon alaisan lati sanwo ki wón tó rí itọju”. Sùgbón awọn oṣiṣẹ ilé ìwòsàn náà ní oro ko rí bè. [1]

Awọn itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]