Latunde Odeku

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
E. Latunde Odeku
Fáìlì:Latunde Odeku.jpg
ÌbíEmanuel Olatunde Alaba Olanrewaju Odeku
(1927-06-29)Oṣù Kẹfà 29, 1927
Lagos, Nigeria
AláìsíAugust 20, 1974(1974-08-20) (ọmọ ọdún 47)
London, England
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian-American
PápáNeurosurgery
Ibi ẹ̀kọ́Howard University
Ó gbajúmọ̀ fúnFirst African neurosurgeon trained in the United States; first neurosurgeon in Nigeria.

E.Latunde Odeku (tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́, Emanuel Olatunde Alaba Olanrewaju Odeku, ni a bí ní ọdún 1927, sí Ìpínlẹ̀ Èkó, orílẹ̀-èdè Naijiria tó sì ṣaláìsí ní ìlú, London, ní ọdún 1974) jẹ́ oníṣẹ́abẹtọpọlọ àkọ́kọ́ tó máa jẹ́ ọmọ Nàìjíríà. United States ni ó ti gbẹ̀kọ́, ó sì fi ìdì iṣẹ́ yìí sọlẹ̀ sí ilẹ̀ Africa.[1][2]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Sanley Finger; Francois Boller; Kenneth L. Tyler (2009). History of Neurology: Handbook of Clinical Neurology (Series Editors: Aminoff, Boller and Swaab). 95. Elsevier. ISBN 978-0-702-0354-18. https://books.google.com/books?id=uTTYCgAAQBAJ&q=Latunde+odeku+Neurosurgery&pg=PA822. 
  2. Adeloye (1975). "E. Latunde Odeku, M.D., F.A.C.S., F.I.C.S., 1927-1974. An African pioneer neurosurgeon". Journal of the National Medical Association (Journal of National Medical Association) 67 (4): 319–320. PMC 2609380. PMID 1099223. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=2609380.