Luisa Diogo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Luisa Diogo

Diogo at the World Economic Forum Annual Meeting 2009.
Alakoso Agba ile Mozambique
President Joaquim Chissano
Armando Guebuza
Asíwájú Pascoal Mocumbi
Arọ́pò Aires Ali
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
Ìbí 11 Oṣù Kẹrin 1958 (1958-04-11) (ọmọ ọdún 56)
Ẹgbẹ́ olóṣèlú Liberation Front
Alma mater Eduardo Mondlane University
School of Oriental and African Studies
Ẹ̀sìn Roman Catholicism[1]

Luísa Dias Diogo (ojoibi April 11, 1958) je Alakoso Agba orile-ede Mozambique lati February 2004 titi di January 2010. O dipo Pascoal Mocumbi, to ti je Alakoso Agba fun odun mesan. Ki o to di Alakoso Agba, o je Alakoso Iseto ati Isuna, ipo to dimu titi di February 2005.[2]Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]